Ajọ NAHCON to n ri si ọrọ irinajo Hajj si ilẹ mimọ niluu Mecca lorilẹede Mecca ti kede iye tawọn eeyan to ba fẹ lọ si Saudi Arabia lọdun yii yoo san. Ninu ifọrọwerọ ti o ...